Lọ́sẹ̀yí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ló ti padà sí ibi tí wọ́n ti wá. Ìfagagbága
náà ti wọ ìpele ‘gbuarter final’.
Àwọn orílẹ̀-èdè tó pegedé, tó ma kó pa níí ìpele yìí ni: BurkinaFaso,
Cameroon, Tunisia, Senegal, D.R. Congo, Morocco, Egypt àti Ghana.
Tunisia ma kojú BurkinaFaso ni ago márùn-ún, ní ago mẹ́jọ alẹ́ ni Senegal
àti Cameroon ma jọ wọ̀yáàjà. Ọjọ́ Àbámẹ́ta ni ìfagagbága ma wáyé.
D.R. Congo ma gbéjà fún Ghana ni ago márùn-ún ìrọ̀lẹ́, Egypt àti Morocco ma
f’àgbà han’ra wọn ní ago mẹ́jọ. ọjọ́ àìkú ni èyí ma wáyé.
No comments:
Post a Comment