Ijọba ipinlẹ
Eko ti fun awọn mẹkaniki to ni ṣọọbu labẹ birigi ati awọn to n taja ni ẹgbẹ
titi ni ọjọ mẹta lati ko ẹru wọn kuro ki wọn to awọn ko, atipe wọn ma fi oju ẹnikeni
ti wọn ba mu a ile-ẹjọ.
Ẹni to n gba
gomina ipinlẹ Eko nimọran nipa CBD, ọgbẹni Agboọla Dabiri sọ pe gbwọn ti ṣetan
lati fọ ipinlẹ Eko mọ toni toni atipe awọn o fẹ mẹkaniki kan kan laẹ birigi pẹlu
awọn ọlọja lẹgbẹ ẹ tit. O royin iwa idọti ti ifufẹ ohun eyi n fa si opopona ni
ilu Eko. Ibi ti wọn ti fẹ bẹrẹ eyi ni Marina to wa ni Island, wọn ni o ṣi ma
ran si awọn agbegbe to ku.

No comments:
Post a Comment