Thursday, December 7, 2017

UEFA CHAMPIONS LEAGUE: ÀWỌN IKỌ̀ TÍ Ó PEGEDÉ FÚN ÌPELE ONÍKỌ̀ MẸ́RÌNDÍNLÓGÚN TÍ A MỌ̀ SÍ ROUND-16


GROUP A
GROUP B
GROUP C
GROUP D
Man United 15
PSG  15
Roma  11
Barca  14
Basel      12
Bayern  15
Chelsea 11
Juventus 11
CSKA   9
Celtic  3
Atletico M 7
Sporting
Benfica   0
Anderlecht 3
Qarabag 2
Olympiacos 1




GROUP A
GROUP B
GROUP C
GROUP D
Liverpool 12
Man City  15
Besiktas  14
Tottenham  16
Sevilla  9
Shakhtar  12
Porto  10
Real Madrid 13
Spartak  6
Napoli  6
RB Leipzig 7
Dortmund  2
Maribor 3
Feyenoord 3
Monaco  2
APOEL  2


Eyi ni abajade ifesewonse ọwọ kọọkan, abajade yii fi han wi pe awọn ikọ ti wọn wa lati Premier League ni wọn mọ bọọlu gba julọ, nitori eyi ni igba akọkọ ti ikọ marun-un lati liigi kan yoo pegede si ipele onikọ merindinlogun (Round-16). Awọn ikọ naa ni; Manchester United, Manchester City, Chelsea, Liverpool ati Tottenham.
Iyikoto fun ipele onikọ mẹrindinlogun to ku naa yoo waye ni Ọjọ aje, Ọsẹ to n bọ.  

No comments:

Post a Comment