Monday, December 11, 2017

ÀWÒRÁN BÍ ' THE FUTURE AWARDS AFRICA ' TI ỌDÚN YÌÍ ṢE LỌ.




Ní opin ọsẹ to kọja yi ni 'The Future Awards Africa' waye ni Federal Palace Hotel, Victoria Island. Ife ẹyẹ yi ni a gbe kalẹ lati yin awọn ọdọ to n ṣe nkan ribi ribi ni ayika wọn.

Aworan die ninu ohun to ṣẹlẹ naa niyi;
















No comments:

Post a Comment