Monday, December 11, 2017

HARRYSONG SỌ KUBU ỌRỌ SI GOMINA IPINLẸ DELTA.











Harrysong  tii ṣe akọrin ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti sọrọ lori rogbodiyan to n ṣẹlẹ laaarin abule meji ni ipinlẹ Delta. Adugbo Aldja ati Igbe Ijaw ti n ba arawọn ja ọjọ ti pẹ amọ ijọba to wa lori aleefa ko fi oju ibẹ woran rara.

Aanu ṣe Harrysong tori Gomina ipinlẹ Delta, Ifeanyi Okowa n ṣowo ni ipinlẹ naa eyi to yẹ ko  ma daabo bo awọn ara ipinlẹ naa to dibo yan si ip. Ija aarinn Urhobo ati Ijaw ni ipinlẹ naa ti pẹ, o si ti sọ ọpọ eniyan di ainile lori.

Ninu nnkaan ti Harrysong fi ṣọwọ si INSTAGRAM ati TWITTER ẹ loni ni pe awọn to n gbe ni agbegbe mejeeji naa nilo adura.

No comments:

Post a Comment