Oludemilade
Martin Alejo ti gbogbo eeyan mọ si Ycee to jẹ ọkan lara awọn akọrin to wa labẹ
Tinny Entertainment. O jẹ akọrin hip hop, lara awọn orin to ti kọ ni; Jagaban, ọmọ
alhaji ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Ohun ti
iroyin jẹ ka mọ nipa ohun ti Ycee sọ ni pe orin ni oun fẹ ma kọ fun araye gbọ
atipe afikun ni awọdu to ba wọle fun oun nigba kugba. O ni ti awọn ololufẹ oun
ba ti n gbadun orin oun o ti tan niyen. Nigba ti o sọrọ de bi awọdu naa ṣe lọ
ni ọdun to kọja lo ṣẹ sọ pe aigba awọdu naa lo mu oun ma joko tara tara ati pe
oun ti gba ikan ni ọdun meji sẹyin.

No comments:
Post a Comment