Ọmọ agbá-bọ́ọ́lù orílẹ̀-èdè England, tó ti gbá bọ́ọ́lù fún chelsea rí
sèpinu lọ́jọ́bọ̀ láti fẹ̀yìntì. Ó tẹ èyí sórí ẹ̀rọ-ayélu-dára ẹ̀. Ó jẹ́ ọmọ ọdún
méjìdínláàdọ́ta.
Lampard gbá bọ́ọ́lù fún Chelsea lẹ́ẹ́gbẹ́ta ìgbà, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti kúrò
níbẹ̀ kó tó fẹ̀yìntì. Ó gbá ayò ọ̀ọ́dúrún s’áwọ̀n, ayò igba ó lé mọ́kànlá ló
gbá nígbàtí ó wà ní Chelsea nínú ọ̀ọ́dúrún ayò tó ní.
Ó ní bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ṣì ń pe òun láti wá gbá bọ́ọ́lù si, òún mọ̀ pé
àkókò fún omi tuntun láti rú lèyí. Ó dúpẹ́ fún àǹfàní láti lọ ní ìmọ̀ akọni-mọ̀ọ́gbá.


No comments:
Post a Comment