Nílùú Èkó, òfin ti de àwọn ajínigbé. Ẹ̀wọ̀n gbére ni ẹni tí ọwọ́ bá tẹ̀ pé
ó jíyángbè, èyí ni òfin tí gómínọ̀ Àḿbọ̀dé fọwọ́ sí. Ó ní tí ẹni tí wọ́n jígbé
bá kú, wọ́n ma pa ajínigbé ọ̀ún nà ni.
Ìjìyà wà fún ẹni tó mọ̀ nípa bí wọ́n ṣe jííyàn gbé, ó wà fún ẹni tó nilé tí wọ́n tọ́jú ẹni tí wọ́n jígbé sí.
No comments:
Post a Comment