Òṣèré tíátà
tí a mọ̀ sí ‘gbogbo Bigs girl’, Ẹniọlá Badmus ni a ri kà gẹ́gẹ́ bí òun alára ṣe
gbe sórí ẹ̀rọ-alátagbà (snapchat) pé òun gba ìwòsàn lọ́wọ́.
Ó fi àwòrán
ara ẹ̀ hàn, ó sì kọ “Health is wealth” tó túmọ̀ sí ‘Ìlera Lọrọ̀’. Ó fi àwòrán ògùn
tó ń lò si.
Kí Olórun
báwa fun ní àláfíà àti ìlera ara pípé.

No comments:
Post a Comment