Ni opin ọsẹ to koja yi ni ẹni to lowo julọ ni ilẹ Adulawọ, Ọgbẹni Aliko Dangote fa ọmọ ẹ fun ọkọ ni ipinlẹ Eko.
GBogbo eeyan to lẹfọn ni eekan-naa ni o wa ni ayẹyẹ igbeyawo naa. Lara wọn ni; igbakeji aarẹ orilẹ-ede Naijiri Ọjọgbọn Oṣibajo Yẹmi, ẹni to wa lara awọn to lowo julọ lagbaye, Bill Gate, Bukọla Saraki, Atiku Abubakar ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Diẹ ninu awọran wọn leyi...







No comments:
Post a Comment