Olorin Hiphop / Rap ọmọ orilẹ-ede Naijiria, Oladipupo Olabode Oladimeji, ti a mọ si ni Oladips ni o gbe orin tuntun jade ti o pe akọle ẹ ni "O SURE". O pe Ọlamide lati ba kọ orin eyi.
O pẹ ti Ọlamide ti kọrin rap gbẹyin eyi jẹ ara ọtun....
Ọladips ft Ọlamide; "O'sure"
No comments:
Post a Comment