Friday, April 20, 2018

Iyawo Akpororo Bi Ibeji



Gbajugbaja apanilẹrin ọmọ orilẹ-ede Naijiria, Akpororo ti pe ara ẹ ni 'Baba Ibeji'.

Eyi ni lati sọ fun gbogbo aye agaga ololufẹ ẹ pe oun ti bi ibeji. Awọn ọmọ yi ni wọn bi si Maryland ni USA. Gẹgẹ bi ibi to wa ṣe fihan lori Instagram to ti sọ iroyin ayọ naa.

No comments:

Post a Comment