E ku ojulona ewi alohun ti n bo lati owo Yusuf Balogun Gemini. Ewi ti a pe oruko re ni "Lagidigba" a bo sile bi owara ojo ni ojo kerinla, osu Erele - eyi ti n se ayajo ololufe kaakiri ilu. Lagidigba je ewi ti o se eye ati ige awon obinrin ile Yoruba, ni yala ewa tabi iwa. Ibalopo asa ati ife ni Lagidigba...
E maa sa lai gba si ori ero yin bi o ba ti jade, ki e si gbo pelu.
Ire o!

No comments:
Post a Comment