Ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí ìbára-enisọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ, GLO tún ti fi hàn pé àwọn lọ̀gá
nínú pípèsè ‘data’ olówó pọ́kú. Wọn ò fún wa ní ‘data’ lówó pọ́kú nìkan, wọń
tún fi ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ si. Ètò náà lọ báyìí:
·
Ta
bá san ẹ̀ẹ́dẹ́gbaajọ náírà (#15,000) , a ma rí 1.4GB lóṣùn tàbí 17GB lọ́dún
kan.
·
Ta
bá san ẹgbàasań náírà (#18,000), a ma rí 1.8GB lóṣùn tàbí 21GB lọ́dún kan.
Àwọn ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ tó tẹ̀lẹ ni:
Innjoo Halo.
Wiko
sunset.
Wiko
Lenny.
Alcatel pixi 3.
Ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ kan ló ma tọ́sí wa ta bá sanwo, kìí ṣe mẹ́rèẹ̀rin. A ó sì ní àǹfàní láti mú nínú oṣooṣù
tàbí ọdún kan.
Wọ́n ti ṣe irú ètò yí rí ní ọdún tó kọjá, kò sì pẹ́ nílẹ̀. Èyí ni pé
ìjáfara léwu.
Fún ìbéèrè, ẹ lè kàn sí:
WEBSITE
FACEBOOK
TWITTER
Fún ìbéèrè, ẹ lè kàn sí:
WEBSITE